Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna

Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona S...

Rafiu Adisa Bello

Share:
Share:
Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani ati Sunna Ojise. O si se alaye ewu ti o wa nibi ki musulumi maa tele awon ti won ba n da adadaale ninu esin. Ni afikun, o tun se alaye awon majemu ti a fi maa nmo adadaale nitori awon iruju ti o wa fun awon Musulumi kan lori re.
Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani...Read More