Awon Idajo Esin Nipa Aja Ati Egbin re

Awon Idajo Esin Nipa Aja Ati Egbin re

Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro

Share:
Share:
Idanileko yi je alaye nipa hadiisi eleekefa ninu tira “Umdatul Ahkaam”. Oludanileko so nipa egbin aja ati awon idajo ti o ro mo o, o si tun so nipa awon agbegbe ti esin ti gba awa Musulumi laaye lati se anfaani lara aja gege bii fifi so ile ati beebee lo
Idanileko yi je alaye nipa hadiisi eleekefa ninu tira “Umdatul Ahkaam”. Oludanileko so nip...Read More