Awon Eko ti o nbe nibi Ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab

Awon Eko ti o nbe nibi Ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab

Rafiu Adisa Bello

Share:
Share:
Alaye waye ninu ibanisoro yi nipa awon eko ti o nbe nibi ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab. Oniwaasi so nipa bi o se je wipe soki ohun ti ipepe Sheikh da le lori ni mimo Olohun ni okan soso ati dida oju ko O ni Oun nikan nibi awon ijosin.
Alaye waye ninu ibanisoro yi nipa awon eko ti o nbe nibi ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-w...Read More